Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọdun kejila Ahasi ọba Juda ni Hoṣea ọmọ Ela bẹ̀rẹ si ijọba ni Samaria, lori Israeli li ọdun mẹsan.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:1-10