Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Assiria si gbọ́ tirẹ̀: nitoriti ọba Assiria gòke wá si Damasku, o si kó o, o si mu u ni igbèkun lọ si Kiri, o si pa Resini.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:1-15