Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahasi si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi: Hesekiah ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:17-20