Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahasi ọba si ké alafo ọnà arin awọn ijoko na, o si ṣi agbada na kuro lara wọn; o si gbé agbada-nla na kalẹ kuro lara awọn malu idẹ ti mbẹ labẹ rẹ̀, o si gbé e kà ilẹ ti a fi okuta tẹ́.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:13-18