Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 14:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tun mu agbègbe ilẹ Israeli pada lati atiwọ̀ Hamati titi de okun pẹ̀tẹlẹ, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa Ọlọrun Israeli, ti o ti sọ nipa ọwọ iranṣẹ rẹ̀ Jona woli, ọmọ Amittai, ti Gat-heferi.

2. A. Ọba 14

2. A. Ọba 14:24-29