Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 14:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoaṣi ọba Israeli si mu Amasiah ọba Juda, ọmọ Jehoaṣi ọmọ Ahasiah ni Betṣemeṣi, o si wá si Jerusalemu, o si wó odi Jerusalemu palẹ lati ẹnu bodè Efraimu titi de ẹnu bodè igun, irinwo igbọnwọ.

2. A. Ọba 14

2. A. Ọba 14:7-20