Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 14:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Amasiah kò fẹ igbọ́. Nitorina Jehoaṣi ọba Israeli gòke lọ; on ati Amasiah ọba Juda si wò ara wọn li oju ni Betṣemeṣi, ti iṣe ti Juda.

2. A. Ọba 14

2. A. Ọba 14:4-13