Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoahasi si bẹ̀ Oluwa, Oluwa si gbọ́ tirẹ̀; nitoriti o ri inira Israeli, nitoriti ọba Siria ni wọn lara.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:1-10