Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoaṣi ọmọ Jehoahasi si tun gbà ilu wọnni pada lọwọ Benhadadi ọmọ Hasaeli, ti o ti fi ogun gbà lọwọ Jehoahasi baba rẹ̀. Igba mẹta ni Joaṣi ṣẹgun rẹ̀, o si gbà awọn ilu Israeli pada.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:24-25