Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si ṣe oju rere si wọn, o si ṣãnu fun wọn, o si ṣe akiyesi wọn, nitoriti majẹmu rẹ̀ pẹlu Abrahamu, Isaaki, ati Jakobu, kò si fẹ run wọn, bẹ̃ni kò si ta wọn nù kuro niwaju rẹ̀ titi di isisiyi.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:22-25