Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi nwọn ti nsinkú ọkunrin kan, si kiye si i, nwọn ri ẹgbẹ́ kan; nwọn si jù ọkunrin na sinu isà-okú Eliṣa; nigbati a si sọ ọ silẹ, ti ọkunrin na fi ara kàn egungun Eliṣa, o si sọji, o si dide duro li ẹsẹ̀ rẹ̀.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:14-25