Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Enia Ọlọrun na si binu si i, o si wipe, Iwọ iba ta lẹrinmarun tabi mẹfa; nigbana ni iwọ iba kọlù Siria titi iwọ iba fi run u: ṣugbọn nisisiyi iwọ o kọlù Siria nigbà mẹta.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:14-25