Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliṣa si ṣe aisàn ninu eyi ti kò ni yè, Joaṣi ọba Israeli si sọ̀kalẹ tọ̀ ọ wá, o si sọkun si i li oju, o si wipe, Baba mi, baba mi! kẹkẹ́ Israeli, ati awọn ẹlẹṣin rẹ̀!

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:8-24