Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 12:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jehoaṣi ọba pè Jehoiada alufa, ati awọn alufa miràn, o si wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ẹnyin kò tun ẹya ile na ṣe? njẹ nisisiyi ẹ máṣe gbà owo mọ lọwọ awọn ojulùmọ nyin, bikòṣepe ki ẹ fi i lelẹ fun ẹya ile na.

2. A. Ọba 12

2. A. Ọba 12:1-12