Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 12:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kò si ba awọn ọkunrin na ṣirò, li ọwọ ẹniti nwọn fi owo na le, lati fi fun awọn ti nṣiṣẹ; nitoriti nwọn ṣe otitọ.

2. A. Ọba 12

2. A. Ọba 12:6-21