Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 12:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ninu owo ti a mu wá sinu ile Oluwa, a kò fi ṣe ọpọ́n fadakà, alumagàji fitila, awokoto, ipè ohun èlo wura tabi ohun elò fadakà kan fun ile Oluwa:

2. A. Ọba 12

2. A. Ọba 12:9-15