Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 12:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati nwọn ri pe, owo pupọ̀ mbẹ ninu apoti na, ni akọwe ọba, ati olori alufa gòke wá, nwọn si dì i sinu apò, nwọn si kà iye owo ti a ri ninu ile Oluwa.

2. A. Ọba 12

2. A. Ọba 12:2-12