Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 12:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. LI ọdun keje Jehu ni Jehoaṣi bẹ̀rẹ si ijọba; ogoji ọdun li o si jọba ni Jerusalemu. Orukọ iyà rẹ̀ a mã jẹ Sibiah ti Beerṣeba.

2. Jehoaṣi si ṣe eyiti o tọ́ li oju Oluwa li ọjọ rẹ̀ gbogbo ninu eyiti Jehoiada alufa nkọ́ ọ.