Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li owurọ̀, o si jade lọ, o si duro, o si wi fun gbogbo awọn enia pe, Olododo li ẹnyin: kiyesi i, emi ṣọ̀tẹ si oluwa mi, mo si pa a: ṣugbọn tani pa gbogbo awọn wọnyi?

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:1-13