Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati iwe na de ọdọ wọn, ni nwọn mu awọn ọmọ ọba, nwọn si pa ãdọrin ọkunrin, nwọn si kó ori wọn sinu agbọ̀n, nwọn si fi wọn ranṣẹ si i ni Jesreeli.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:4-12