Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehu si lọ, ati Jehonadabu ọmọ Rekabu sinu ile Baali, o si wi fun awọn olùsin Baali pe, Ẹ wá kiri, ki ẹ si wò ki ẹnikan ninu awọn iranṣẹ Oluwa ki o má si pẹlu nyin nihin, bikòṣe kìki awọn olùsin Baali.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:16-33