Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehu si ranṣẹ si gbogbo Israeli; gbogbo awọn olùsin Baali si wá tobẹ̃ ti kò si kù ọkunrin kan ti kò wá. Nwọn si wá sinu ile Baali; ile Baali si kún lati ikangun ekini titi de ekeji.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:14-23