Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Jehu pa gbogbo awọn ti o kù ni ile Ahabu ni Jesreeli ati gbogbo awọn enia nla rẹ̀, ati awọn ibatan rẹ̀, ati awọn alufa rẹ̀, titi on kò fi kù ọkan silẹ fun u.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:4-12