Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 1:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahasiah si ṣubu lãrin fèrese ọlọnà kan ni iyara òke rẹ̀ ti o wà ni Samaria, o si ṣàisan: o si rán awọn onṣẹ o si wi fun wọn pe, Ẹ lọ, ẹ bère lọwọ Baalsebubu, oriṣa Ekroni, bi emi o là ninu aisan yi.

2. A. Ọba 1

2. A. Ọba 1:1-10