Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 1:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, iná sọ̀kalẹ lati ọrun wá, o si run olori-ogun meji arãdọta iṣãju pẹlu arãdọta wọn: njẹ nisisiyi, jẹ ki ẹmi mi ki o ṣọwọn li oju rẹ.

2. A. Ọba 1

2. A. Ọba 1:9-18