Yorùbá Bibeli

Ifi 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o ba ṣẹgun, on na li a o fi aṣọ funfun wọ̀; emi kì yio pa orukọ rẹ̀ rẹ́ kuro ninu iwe ìye, ṣugbọn emi o jẹwọ orukọ rẹ̀ niwaju Baba mi, ati niwaju awọn angẹli rẹ̀.

Ifi 3

Ifi 3:4-13