Yorùbá Bibeli

Ifi 21:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ni odi nla ati giga, o si ni ẹnubode mejila, ati ni awọn ẹnubode na angẹli mejila ati orukọ ti a kọ sara wọn ti iṣe orukọ awọn ẹ̀ya mejila ti awọn ọmọ Israeli:

Ifi 21

Ifi 21:4-17