Yorùbá Bibeli

Ifi 20:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si jade lọ lati mã tàn awọn orilẹ-ède ti mbẹ ni igun mẹrẹrin aiye jẹ, Gogu ati Magogu, lati gbá wọn jọ si ogun: awọn ti iye wọn dabi iyanrìn okun.

Ifi 20

Ifi 20:7-12