Yorùbá Bibeli

Ifi 2:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ikú pa awọn ọmọ rẹ̀; gbogbo ijọ ni yio si mọ̀ pe, emi li ẹniti nwadi inu ati ọkàn: emi o si fifun olukuluku nyin gẹgẹ bi iṣẹ nyin.

Ifi 2

Ifi 2:13-27