Yorùbá Bibeli

Ifi 16:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yinyín nla, ti ọkọ̃kan rẹ̀ to talenti ni ìwọ̀n, si bọ́ lù awọn enia lati ọrun wà: awọn enia si sọ̀rọ-òdi si Ọlọrun nitori iyọnu yinyín na; nitoriti iyọnu rẹ̀ na pọ̀ gidigidi.

Ifi 16

Ifi 16:19-21