Yorùbá Bibeli

Ifi 16:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ẹmi èṣu ni wọn, ti nṣe iṣẹ-iyanu, awọn ti njade lọ sọdọ awọn ọba gbogbo ilẹ aiye, lati gbá wọn jọ si ogun ọjọ nla Ọlọrun Olodumare.

Ifi 16

Ifi 16:5-19