Yorùbá Bibeli

Ifi 14:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si ri angẹli miran nfò li agbedemeji ọrun, ti on ti ihinrere ainipẹkun lati wãsu fun awọn ti ngbé ori ilẹ aiye, ati fun gbogbo orilẹ, ati ẹya, ati ède, ati enia,

Ifi 14

Ifi 14:3-14