Yorùbá Bibeli

Ifi 13:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si ri ọkan ninu awọn ori rẹ̀ bi ẹnipe a sá a pa, a si ti wo ọgbẹ aṣapa rẹ̀ na san, gbogbo aiye si fi iyanu tẹle ẹranko na.

Ifi 13

Ifi 13:1-10