Yorùbá Bibeli

Ifi 1:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi Johanu, arakunrin nyin ati alabapin pẹlu nyin ninu wahala ati ijọba ati sũru ti mbẹ ninu Jesu, wà ninu erekuṣu ti a npè ni Patmo, nitori ọ̀rọ Ọlọrun, ati nitori ẹrí Jesu Kristi.

Ifi 1

Ifi 1:5-14