Yorùbá Bibeli

Ifi 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, o mbọ̀ ninu awọsanma; gbogbo oju ni yio si ri i, ati awọn ti o gún u li ọ̀kọ pẹlu; ati gbogbo orilẹ-ede aiye ni yio si mã pohùnrere ẹkún niwaju rẹ̀. Bẹ̃na ni. Amin.

Ifi 1

Ifi 1:6-12