Yorùbá Bibeli

1. Tim 5:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹlu nwọn nkọ́ lati ṣe ọlẹ, lati mã kiri lati ile de ile; ki iṣe ọlẹ nikan, ṣugbọn onisọkusọ ati olofòfo pẹlu, nwọn a ma sọ ohun ti kò yẹ.

1. Tim 5

1. Tim 5:6-23