Yorùbá Bibeli

1. Tim 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mã ṣe itọju ara rẹ ati ẹkọ́ rẹ; mã duro laiyẹsẹ ninu nkan wọnyi: nitori ni ṣiṣe eyi, iwọ ó gbà ara rẹ ati awọn ti ngbọ́ ọ̀rọ rẹ là.

1. Tim 4

1. Tim 4:13-16