Yorùbá Bibeli

1. Tim 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ gẹgẹ li o yẹ fun awọn obinrin lati ni iwa àgba, kì nwọn má jẹ asọrọ-ẹni-lẹhin bikoṣe alairekọja, olõtọ li ohun gbogbo.

1. Tim 3

1. Tim 3:10-12