Yorùbá Bibeli

1. Tim 1:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi mo ti gba ọ niyanju lati joko ni Efesu, nigbati mo nlọ si Makedonia, ki iwọ ki o le paṣẹ fun awọn kan, ki nwọn ki o máṣe kọ́ni li ẹkọ́ miran,

1. Tim 1

1. Tim 1:1-8