Yorùbá Bibeli

1. Pet 2:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin ti kì iṣe enia nigbakan rí, ṣugbọn nisisiyi ẹnyin di enia Ọlọrun, ẹnyin ti kò ti ri ãnu gbà ri, ṣugbọn nisisiyi ẹ ti ri ãnu gbà.

1. Pet 2

1. Pet 2:2-11