Yorùbá Bibeli

1. Kro 9:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti awọn ọmọ Lefi wọnyi jẹ awọn olori adena mẹrin, nwọn si wà ninu iṣẹ na, nwọn si wà lori iyara ati ibi iṣura ile Ọlọrun.

1. Kro 9

1. Kro 9:16-35