Yorùbá Bibeli

1. Kro 9:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo wọnyi ti a ti yàn lati ṣe adena loju iloro, jẹ igba o le mejila. A ka awọn wọnyi nipa idile wọn ni ileto wọn, awọn ẹniti Dafidi ati Samueli, ariran, ti yàn nitori otitọ wọn.

1. Kro 9

1. Kro 9:19-25