Yorùbá Bibeli

1. Kro 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

A si ka iye gbogbo Israeli ni idile idile wọn; si kiyesi i, a kọ wọn sinu iwe awọn ọba Israeli: Juda li a si kó lọ si Babiloni nitori ẹ̀ṣẹ rẹ̀.

1. Kro 9

1. Kro 9:1-3