Yorùbá Bibeli

1. Kro 6:65 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si fi keké fi ilu wọnyi ti a da orukọ wọn fun ni lati inu ẹ̀ya awọn ọmọ Juda, ati lati inu ẹ̀ya awọn ọmọ Simeoni, ati lati inu ẹ̀ya awọn ọmọ Benjamini.

1. Kro 6

1. Kro 6:57-69