Yorùbá Bibeli

1. Kro 6:60 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lati inu ẹ̀ya Benjamini; Geba pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Alemeti pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Anatoti pẹlu ìgberiko rẹ̀. Gbogbo ilu wọn ni idile wọn jẹ ilu mẹtala.

1. Kro 6

1. Kro 6:58-63