Yorùbá Bibeli

1. Kro 29:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia si yọ̀, nitori nwọn fi tinutinu ṣe iranlọwọ nitori pẹlu ọkàn pipe ni nwọn fi tinutinu ṣe iranlọwọ fun Oluwa: pẹlupẹlu Dafidi ọba si yọ̀ gidigidi.

1. Kro 29

1. Kro 29:1-11