Njẹ iṣe Dafidi ọba, ibẹ̀rẹ ati ikẹhin, kiyesi i, a kọ ọ sinu iwe Samueli ariran, ati sinu iwe itan Natani woli, ati sinu iwe itan Gadi ariran.