Yorùbá Bibeli

1. Kro 29:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si sọ fun gbogbo ijọ enia pe, Nisisiyi ẹ fi iyìn fun Oluwa Ọlọrun nyin. Gbogbo enia si fi iyìn fun Oluwa Ọlọrun awọn baba wọn, nwọn si tẹ ori wọn ba, nwọn wolẹ fun Oluwa ati ọba.

1. Kro 29

1. Kro 29:19-23