Yorùbá Bibeli

1. Kro 29:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tirẹ Oluwa ni titobi, ati agbara, ati ogo, ati iṣẹgun, ati ọlá-nla: nitori ohun gbogbo li ọrun ati li aiye tirẹ ni; ijọba ni tirẹ, Oluwa, a si gbé ọ leke li ori fun ohun gbogbo.

1. Kro 29

1. Kro 29:9-16