Yorùbá Bibeli

1. Kro 29:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

DAFIDI ọba si wi fun gbogbo ijọ enia pe, Solomoni ọmọ mi, on nikan ti Ọlọrun ti yàn, jẹ ọmọde o si rọ̀, iṣẹ na si tobi: nitori ti ãfin na kì iṣe fun enia, ṣugbọn fun Ọlọrun Oluwa.

1. Kro 29

1. Kro 29:1-8